Isaiah 3:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọdọmọkunrin ni OLUWA yóo fi jẹ olórí wọn, àwọn ọmọde ni yóo sì máa darí wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn ọmọde li emi o fi ṣe ọmọ-alade wọn, awọn ọmọ-ọwọ ni yio si ma ṣe akoso wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi ó sọ àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin di aláṣẹ wọn, ọ̀dọ́mọdé lásán làsàn ni yóò sì máa jọba lóríi wọn.