Isaiah 30:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí náà, Ẹni Mímọ́ Israẹli ní: “Nítorí pé ẹ kẹ́gàn ọ̀rọ̀ yìí, ẹ gbẹ́kẹ̀lé ìninilára ati ẹ̀tàn, ẹ sì gbára lé wọn,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina bayi li Ẹni-Mimọ Israeli wi, Nitoriti ẹnyin gàn ọ̀rọ yi, ti ẹnyin si gbẹkẹle ininilara on ìyapa, ti ẹnyin si gbe ara nyin lé e;
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí náà, èyí ni ohun tí Ẹni-Mímọ́ Ísírẹ́lì wí: “Nítorí pé ẹ ti kọ ọ̀rọ̀ yìí sílẹ̀, ẹ gbáralé ìnilára kí ẹ sì gbọ́kànlé ẹ̀tàn,