Isaiah 30:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
nítorí náà, ẹ̀ṣẹ̀ tí ẹ̀ ń dá yìí; yóo dàbí ògiri gíga tí ó là, tí ó sì fẹ́ wó; lójijì ni yóo wó lulẹ̀ lẹ́ẹ̀kanṣoṣo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni aiṣedede yi yio ri si nyin bi odi yiya ti o mura ati ṣubu, ti o tiri sode lara ogiri giga, eyiti wiwó rẹ̀ de lojijì, lojukanna.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
ẹ̀ṣẹ̀ yìí yóò rí fún ọ gẹ́gẹ́ bí ògiri gíga, tí ó sán tí ó sì fì tí ó sì wó lójijì, àti ńi ìṣẹ́jú àáyá.