Isaiah 30:2 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wọ́n múra, wọ́n gbọ̀nà Ijipti láì bèèrè ìmọ̀ràn lọ́dọ̀ mi. Wọ́n lọ sápamọ́ sí abẹ́ ààbò Farao, wọ́n lọ wá ààbò ní Ijipti.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ti nwọn nrìn lọ si Egipti, ṣugbọn ti nwọn kò bere li ẹnu mi; lati mu ara wọn le nipa agbara Farao, ati lati gbẹkẹle ojiji Egipti!
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
tí wọ́n lọ sí Éjíbítì láì ṣe fún mi, tí ó ń wá ìrànlọ́wọ́ lọ́dọ̀ Fáráò fún ààbò, sí òjìji, Éjíbítì fún ibi ìsádi.