Isaiah 30:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Nítorí náà, ààbò Farao yóo di ìtìjú fún wọn, ibi ìpamọ́ abẹ́ Ijipti yóo di ìrẹ̀sílẹ̀ fún wọn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitorina ni agbara Farao yio ṣe jẹ itiju nyin, ati igbẹkẹle ojiji Egipti yio jẹ idãmu nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n ààbò Fáráò yóò já sí ìtìjú fún un yín, òjìji Éjíbítì yóò mú àbùkù báa yín.