Isaiah 30:31 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìbẹ̀rù-bojo yóo mú àwọn ará Asiria nígbà tí wọ́n bá gbóhùn OLUWA, nígbà tí ó bá fi kùmọ̀ rẹ̀ lù wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori nipa ohùn Oluwa li a o fi lù awọn ara Assiria bo ilẹ, ti o fi kùmọ lù.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ohùn OLÚWA yóò fọ́ Áṣíríà túútúú, pẹ̀lú ọ̀pá aládé rẹ̀ ni yóò lù wọ́n bolẹ̀.