Isaiah 30:4 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn olórí wọn ti lọ sí Soani, tí àwọn ikọ̀ wọn sì ti dé Hanesi.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori awọn olori rẹ̀ wá ni Soani, awọn ikọ̀ rẹ̀ de Hanesi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí wọ́n tilẹ̀ ní àwọn òṣìṣẹ́ ní Sóánì tí àwọn ikọ̀ wọn sì ti dé sí Hánísì,