Isaiah 31:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Bẹ́ẹ̀ ni ó gbọ́n, ó sì mọ ọ̀nà tí ó fi lè mú kí àjálù dé bá eniyan, kì í sọ̀rọ̀ tán, kó yí ọ̀rọ̀ rẹ̀ pada. Ṣugbọn yóo dìde sí ìdílé àwọn aṣebi, ati àwọn tí ń ti àwọn oníṣẹ́ ẹ̀ṣẹ̀ lẹ́yìn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn on gbọ́n pẹlu, o si mu ibi wá, kì yio si dá ọ̀rọ rẹ̀ padà: on si dide si ile awọn oluṣe buburu, ati si oluranlọwọ awọn ti nṣiṣẹ aiṣedede.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣíbẹ̀ṣíbẹ̀ òun pẹ̀lú jẹ́ ọlọgbọ́n ó sì lè mú ìparun wá; òun kì í kó ọ̀rọ̀ rẹ̀ jẹ. Òun yóò dìde sí ilé àwọn ìkà, àti sí àwọn tí ń ṣe ìrànlọ́wọ́ fún aṣebi.