Isaiah 31:7 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Nítorí pé ní ọjọ́ náà, olukuluku yóo gbé àwọn ère fadaka ati ère wúrà tí ó fi ọwọ́ rẹ̀ ṣe sọnù, àwọn ère tí ó mú wọn dẹ́ṣẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori li ọjọ na ni olukuluku enia yio jù ere fadaka rẹ̀, ati ere wura rẹ̀ nù, ti ọwọ́ ẹnyin tikara nyin ti ṣe fun ẹ̀ṣẹ fun nyin.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí ní ọjọ́ náà, ẹnì kọ̀ọ̀kan yín yóò kọ àwọn ère fàdákà àti wúrà tí ọwọ́ ẹ̀ṣẹ̀ẹ yín ti ṣe.