Isaiah 32:13 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
nítorí ẹ̀gún ẹ̀wọ̀n ati ẹ̀gún ọ̀gàn ni ó ń hù lórí ilẹ̀ àwọn eniyan mi. Bákan náà, ẹ káàánú fún àwọn ilé aláyọ̀ ninu ìlú tí ó kún fún ayọ̀,
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹgún ọ̀gan on òṣuṣu yio wá sori ilẹ awọn enia mi; nitõtọ, si gbogbo ile ayọ̀ ni ilu alayọ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
àti fún ilẹ̀ àwọn ènìyàn mi ilẹ̀ tí ó ti kún fún ẹ̀gún àti ẹ̀wọ̀n— bẹ́ẹ̀ ni, kẹ́dùn fún gbogbo ilé ìtura àti fún ìlú àríyá yìí.