Isaiah 32:16 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
A óo máa ṣe ìdájọ́ ẹ̀tọ́ ní gbogbo ilẹ̀ náà, ìwà òdodo yóo sì wà níbi gbogbo.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni idajọ yio ma gbe aginju; ati ododo ninu ilẹ eleso.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀tọ́ yóò máa gbé ní inú aṣálẹ̀ àti òdodo yóò sì máa gbé ní pápá oko ọlọ́ràá.