Isaiah 32:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Yìnyín yóo bọ́, yóo bo gbogbo ilẹ̀, a óo sì pa ìlú náà run patapata.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn yio rọ̀ yìnyín, nigbati igbó nṣubu lulẹ; ati ni irẹlẹ a o rẹ̀ ilu na silẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé yìnyín ti tẹ́jú igbó pẹrẹṣẹ àti tí ojú ìlú ti tẹ́ pẹrẹṣẹ pátapáta,