Isaiah 32:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn tí wọ́n bá rí i kò ní dijú sí i, etí àwọn tí ó gbọ́ ọ kò ní di.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oju awọn ẹniti o riran kì yio ṣe baibai, ati eti awọn ti o ngbọ́ yio tẹ́ silẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nígbà náà ni ojú àwọn tí ó rí kò ní pàdé mọ́, àti etí àwọn tí ó gbọ́ yóò tẹ́tí sílẹ̀.