Isaiah 32:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Kìkì ibi ni èrò inú àwọn eniyankeniyan. Wọn a máa pète ìkà, láti fi irọ́ pa àwọn talaka run, kì báà jẹ́ pé ẹjọ́ aláìní jàre.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ibi ni gbogbo ohun-elò enia-kenia jẹ pẹlu: on gbà èro buburu, lati fi ọ̀rọ eke pa talaka run, bi alaini tilẹ nsọ õtọ ọ̀rọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìlànà àwọn aṣa jẹ ti ìkà, ó pète oríṣìí ìlànà ibi láti pa aláìní run pẹ̀lú irọ́ bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀bẹ̀ òtòsì sì tọ̀nà.