Isaiah 33:12 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn orílẹ̀-èdè yóo dàbí ìgbà tí a sun wọ́n, tí wọ́n di eérú, àní bí igi ẹ̀gún tí a gé lulẹ̀, tí a sì dáná sun.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn enia yio si dabi sisun ẽru, bi ẹgún ti a ké ni nwọn o jo ninu iná.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
A ó jó àwọn ènìyàn run bí eérú; bí igbó ẹ̀gún tí a gé la ó dáná sí wọn.”