Isaiah 33:19 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ kò ní rí àwọn aláfojúdi náà mọ́, àwọn tí wọn ń fọ èdè tí kò ní ìtumọ̀ si yín, tí wọn ń kólòlò ní èdè tí ẹ kò gbọ́.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ kì yio ri awọn enia ti o muná; awọn enia ti ọ̀rọ wọn jinlẹ jù eyiti iwọ le gbọ́, ti ahọn wọn ṣe ololò, ti kò le ye ọ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìwọ kì yóò rí àwọn agbéraga ènìyàn wọ̀nyẹn mọ́, àwọn ènìyàn tí èdè wọn farasin, pẹ̀lú ahọ́n tí ó ṣàjèjì tí kò sì yéni.