Isaiah 33:24 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kò sí ará ìlú kan tí yóo sọ pé, “Ara mi kò yá.” A óo dárí ẹ̀ṣẹ̀ àwọn tí ń gbé ibẹ̀ jì wọ́n.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati awọn ará ibẹ̀ ki yio wipe, Ara mi kò yá: a o dari aiṣedede awọn enia ti ngbe ibẹ jì wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kò sí ẹnikẹ́ni tí ó ń gbé Ṣíhónì tí yóò wí pé, “èmi ń sàìsàn,” àti gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ àwọn tí ń gbé ibẹ̀ ni a ó fojúfòdá.