Isaiah 33:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn orílẹ̀-èdè sá nígbà tí wọ́n gbọ́ ariwo tí ó dàbí ti ààrá, wọ́n fọ́n ká nígbà tí o gbéra nílẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Li ariwo irọ́kẹ̀kẹ li awọn enia sá, ni gbigbe ara rẹ soke li a fọ́n awọn orilẹ-ède ká.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ìkérara ohùn rẹ, àwọn ènìyàn sá, nígbà tí o dìde sókè, àwọn orílẹ̀ èdè fọ́nká.