Isaiah 33:4 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
A kó ìkógun jọ bí ìgbà tí tata bo oko, àwọn eniyan dà bo ìṣúra, bí ìgbà tí eṣú bo oko.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A o si ṣà ikogun nyin jọ bi ikojọ awọn ẹlẹngà: bi isure siwa, isure sẹhìn awọn eṣú, li on o sure si wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ìkógun rẹ, ìwọ orílẹ̀ èdè ni a kórè gẹ́gẹ́ bí i ti ọ̀dọ́ eṣú; gẹ́gẹ́ bí àkójọpọ̀ eṣú, àwọn ènìyàn bọ́ lù ú.