Isaiah 33:9 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ilẹ̀ ṣófo ó sì gbẹ, ìtìjú bá òkè Lẹbanoni, gbogbo ewéko orí rẹ̀ sì rẹ̀ dànù. Ṣaroni dàbí aṣálẹ̀, igi igbó Baṣani ati ti òkè Kamẹli sì wọ́wé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ilẹ ngbawẹ̀ o si njoro, oju ntì Lebanoni o si rọ: Ṣaroni dabi aginju; ati Baṣani ati Karmeli gbọ̀n eso wọn danù.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ilẹ̀ ṣọ̀fọ̀ ó sì ṣòfò dànù, ojú ti Lẹ́bánónì ó sì ṣá Ṣárónì sì dàbí aginjù, àti Báṣánì òun Kámẹ́lì rẹ àwọn èwe wọn.

Recommended Reading