Isaiah 36:3 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Eliakimu, ọmọ Hilikaya tí ó jẹ́ alákòóso ààfin jáde lọ bá wọn pẹlu Ṣebina, akọ̀wé ilé ẹjọ́, ati Joa ọmọ Asafu, akọ̀wé ààfin.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Eliakimu ọmọ Hilkia, olùtọ́ju ile, jade tọ̀ ọ wá, pẹlu Ṣebna akọwe, ati Joa ọmọ Asafu, akọwe iranti.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Eliákímù ọmọ Hílíkáyà alábojútó ààfin, Ṣébínà akọ̀wé, àti Jóà ọmọ Áṣáfù akọ̀wé jáde lọ pàdé rẹ̀.
Recommended Reading