Isaiah 37:25 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Mo gbẹ́ kànga mo sì mu omi ninu wọn. Mo ti fi ẹsẹ̀ mi tẹ gbogbo omi odò kéékèèké ilẹ̀ Ijipti ní àtẹ̀gbẹ.’
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi ti wà kanga, mo si ti mu omi; atẹlẹsẹ mi ni mo si ti fi mu gbogbo odò ibi ihamọ gbẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi ti gbẹ́ kàǹga ní ilẹ̀ àjèjì mo sì mu omi ní ibẹ̀, pẹ̀lú àtẹ́lẹṣẹ̀ mi Èmi ti gbẹ́ gbogbo omi àwọn odò Éjíbítì.’