Isaiah 37:26 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Ṣé o kò tíì gbọ́ pé láti ìgbà pípẹ́, ni mo ti pinnu ohun tí mò ń mú ṣẹ nisinsinyii? Láti ayébáyé ni mo ti ṣètò rẹ̀, pé kí o wó ìlú olódi palẹ̀, kí ó di òkítì àlàpà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Iwọ kò ti gbọ́ ri pe, lai emi li o ti ṣe e, ati pe emi li o ti dá a nigba atijọ? nisisiyi mo mu u ṣẹ, ki iwọ ki o sọ ilu-nla olodi dahoro, di okiti iparun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ṣé o kò tí ì gbọ́? Tipẹ́ tipẹ́ ni mo ti fìdíi rẹ̀ mulẹ̀. Láti ìgbà pípẹ́ ni mo ti ṣètò rẹ̀; ní àkókò yìí ni mo mú wá sí ìmúṣẹ, pé o ti sọ àwọn ìlú olódi di àkójọpọ̀ àwọn òkúta