Isaiah 37:31 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn ọmọ Juda tí ó bá ṣẹ́kù yóo fi gbòǹgbò múlẹ̀, wọn óo sì so èso.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ati iyokù ti o sala ninu ile Juda yio tun fi gbòngbo mulẹ nisalẹ, yio si so eso loke:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́ẹ̀kan sí i, àṣẹ́ku láti ilé Júdà yóò ta gbòǹgbò níṣàlẹ̀ yóò sì ṣo èṣo lókè.