Isaiah 37:32 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Àwọn eniyan yóo ṣẹ́kù tí yóo wá láti Jerusalẹmu àwọn tí wọn yóo sá àsálà yóo wá láti orí òkè Sioni. Ìtara OLUWA àwọn ọmọ ogun ni yóo ṣe èyí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori lati Jerusalemu ni iyokù yio jade lọ, ati awọn ti o sala lati oke Sioni wá: itara Oluwa awọn ọmọ-ogun yio ṣe eyi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítorí láti Jérúsálẹ́mù ni àwọn àṣẹ́kù yóò ti wá, àti láti òkè Ṣíhónì ni ikọ̀ àwọn tí ó sálà. Ìtara OLÚWA àwọn ọmọ-ogun ni yóò mú èyí ṣẹ.