Isaiah 37:35 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
N óo dáàbò bo ìlú yìí, n óo sì gbà á sílẹ̀ nítorí tèmi ati nítorí Dafidi iranṣẹ mi.’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nitori emi o dãbo bò ilu yi lati gbà a nitoriti emi tikala mi, ati nitoriti Dafidi iranṣẹ mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Èmi yóò dáàbò bo ìlú yìí èmi ó sì gbàá là, nítorí mi àti nítoríì Dáfídì ìránṣẹ́ mi!”
Recommended Reading