Isaiah 37:6 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Aisaya dá wọn lóhùn pé, “Ẹ wí fún oluwa yín pé OLUWA ní: ‘Má bẹ̀rù nítorí ọ̀rọ̀ tí o gbọ́ tí iranṣẹ ọba Asiria sọ tí ó ń fi mí ṣe ẹlẹ́yà.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Isaiah si wi fun wọn pe, Bayi ni ki ẹ wi fun oluwa nyin, pe, Bayi ni Oluwa wi, Máṣe bẹ̀ru ọ̀rọ ti iwọ ti gbọ́, nipa eyiti awọn iranṣẹ ọba Assiria ti fi sọ̀rọ buburu si mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àìṣáyà sọ fún wọn pé, “Ẹ sọ fún ọ̀gá yín pé, ‘Ohun tí OLÚWA sọ nìyìí: Má ṣe bẹ̀rù ohun tí ẹ ti gbọ́ gbogbo ọ̀rọ̀ tí ọba Ásíríà tí ó wà nínú ìdè ti fi sọ̀rọ̀ òdì sí mi.