Isaiah 37:7 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ìwọ máa wò ó, n óo fi ẹ̀mí kan sí inú rẹ̀, yóo gbọ́ ìròyìn èké kan, yóo sì pada lọ sí ilẹ̀ rẹ̀. Nígbà tí ó bá dé ilé n óo jẹ́ kí wọ́n fi idà pa á.’ ”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Wò o, emi o fi ẽmi kan sinu rẹ̀, on o si gbọ́ iró kan, yio si pada si ilu on tikalarẹ̀; emi o si mu ki o ti ipa idà ṣubu ni ilẹ on tikalarẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Tẹ́tísílẹ̀! Èmi yóò fi ẹ̀mí kan sínú rẹ̀ tó bẹ́ẹ̀ tí ó fi jẹ́ pé bí o bá ti gbọ́ ìròyìn kan, òun yóò padà sí orílẹ̀ èdè rẹ̀, níbẹ̀ ni n ó sì ti jẹ́ kí wọn ké e lulẹ̀ pẹ̀lú idà.’ ”