Isaiah 38:11 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
***
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo ni, emi kì yio ri Oluwa, ani Oluwa, ni ilẹ alãyè: emi kì yio ri enia mọ lãrin awọn ti ngbé ibi idakẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi wí pé, “Èmi kì yóò lè tún rí OLÚWA mọ́, àni OLÚWA, ní ilẹ̀ àwọn alààyè; èmi kì yóò lè síjú wo ọmọnìyàn mọ́, tàbí kí n wà pẹ̀lú àwọn tí ó sì ń gbe orílẹ̀ ayé báyìí.