Isaiah 38:13 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
***
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Mo ṣirò titi di òwurọ, pe, bi kiniun, bẹ̃ni yio fọ́ gbogbo egungun mi; lati ọ̀san de oru ni iwọ o mu mi de òpin mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi fi ṣùúrù dúró títí di àfẹ̀mọ́jú, ṣùgbọ́n gẹ́gẹ́ bí kìnnìún ó ti fọ́ gbogbo egungun mi; ọ̀ṣán àti òru ni ìwọ fi ṣe òpin mi.