Isaiah 38:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
***
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kili emi o wi? o ti sọ fun mi, on tikalarẹ̀ si ti ṣe e: emi o ma lọ jẹjẹ fun gbogbo ọdun mi ni kikorò ọkàn mi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n kí ni èmi lè sọ? Òun ti bá mi ṣọ̀rọ̀ àti pé òun tìkálára rẹ̀ ló ti ṣe èyí. Èmi yóò máa rìn ní ìrẹ̀lẹ̀ ní gbogbo ọjọ́ mi nítorí ìpọ́njú ẹ̀mí mi yìí.