Isaiah 38:17 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
***
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, mo ti ni ikorò nla nipò alafia: ṣugbọn iwọ ti fẹ́ ọkàn mi lati ihò idibàjẹ wá: nitori iwọ ti gbe gbogbo ẹ̀ṣẹ mi si ẹ̀hin rẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Nítòótọ́ fún àǹfààní mi ni pé mo jẹ ìyà irú ìpọ́njú báyìí. Nínú ìfẹ́ rẹ ni o pamí mọ́ kúrò nínú ọ̀gbun ìparun; ìwọ sì ti fi gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ mi sí ẹ̀yìn rẹ.