Isaiah 38:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
***
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Oluwa mura tan lati gbà mi: nitorina a o kọ orin mi lara dùrù olokùn, ni gbogbo ọjọ aiye wa ni ile Oluwa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
OLÚWA yóò gbà mí là bẹ́ẹ̀ ni àwa yóò sì kọrin pẹ̀lú ohun èlò olókun ní gbogbo ọjọ́ ayé wa nínú tẹ́ḿpìlì ti OLÚWA.