Isaiah 39:3 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Lẹ́yìn náà Aisaya wolii tọ Hesekaya ọba lọ, ó bi í pé, “Kí ni àwọn ọkunrin wọnyi wí, láti ibo ni wọ́n sì ti wá sọ́dọ̀ rẹ?” Hesekaya dáhùn, ó ní, “Láti ilẹ̀ òkèèrè, ní Babiloni ni wọ́n ti wá.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni wolĩ Isaiah wá sọdọ Hesekiah ọba, o si wi fun u pe, Kini awọn ọkunrin wọnyi wi? ati lati ibo ni nwọn ti wá sọdọ rẹ? Hesekiah si wi pe, Lati ilẹ jijin ni nwọn ti wá sọdọ mi, ani lati Babiloni.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn náà wòlíì Àìṣáyà lọ sí ọ̀dọ̀ Heṣekáyà ọba ó sì béèrè pé, “Kí ni àwọn ènìyàn wọ̀nyí wí, níbo ni wọ́n sì ti wá?” “Láti ilẹ̀ jínjìnnà,” ni èsì Heṣekáyà. “Wọ́n wá sọ́dọ̀ mi láti Bábílónì.”