Isaiah 39:5 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Aisaya bá sọ fún Hesekaya, pé, “Gbọ́ ohun tí OLUWA àwọn ọmọ ogun wí:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nigbana ni Isaiah wi fun Hesekiah pe, Gbọ́ ọ̀rọ Oluwa awọn ọmọ-ogun:
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn náà ni Àìṣáyà sọ fún Heṣekáyà pé, “Gbọ́ ọ̀rọ̀ OLÚWA àwọn ọmọ-ogun: