Isaiah 4:1 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Tí ó bá di ìgbà náà, obinrin meje yóo rọ̀ mọ́ ọkunrin kan ṣoṣo, wọn óo máa bẹ̀ ẹ́ pé, “A óo máa bọ́ ara wa, a óo sì máa dá aṣọ sí ara wa lọ́rùn. Ṣá máa jẹ́ ọkọ wa, kí á máa jẹ́ orúkọ rẹ; kí o mú ìtìjú kúrò lọ́rọ̀ wa.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
ATI li ọjọ na obinrin meje yio dimọ́ ọkunrin kan, wipe, Awa o jẹ onjẹ ara wa, awa o si wọ̀ aṣọ ara wa: kìkì pe, jẹ ki a fi orukọ rẹ pè wa, lati mu ẹgàn wa kuro.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ní ọjọ́ náà, obìnrin méje yóò dì mọ́ ọkunrin kan yóò sì wí pé, “Àwa ó má a jẹ oúnjẹ ara wa a ó sì pèsè aṣọ ara wa; sáà jẹ́ kí a má a fi orúkọ rẹ̀ pè wá. Mú ẹgan wá kúrò!”