Isaiah 4:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
ní ọ̀sán, yóo mú kí ìkùukùu bo gbogbo òkè Sioni ati àwọn tí ó ń péjọ níbẹ̀; ní alẹ́, yóo sì fi èéfín ati ìtànṣán ìmọ́lẹ̀ bò wọ́n. Ògo OLUWA yóo bò wọ́n bí àtíbàbà ati ìbòrí.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Lori olukuluku ibùgbe oke Sioni, ati lori awọn apejọ rẹ̀, li Oluwa yio si da awọsanma, ati ẹ̃fin li ọsan, ati didan ọwọ́ iná li oru: nitori àbò yio wá lori gbogbo ogo.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Lẹ́yìn náà, OLÚWA yóò dá sorí òkè Síhónì àti sóríi gbogbo àwọn tí ó péjọ pọ̀ ṣíbẹ̀, kúrúkúrú èéfín ní ọ̀ṣán àti ìtànsán ọ̀wọ́ iná ní òru, lórí gbogbo ògo yìí ni ààbò yóò wà.