Isaiah 40:1 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ọlọrun yín ní, “Ẹ tù wọ́n ninu, ẹ tu àwọn eniyan mi ninu.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹ tù enia mi ninu, ẹ tù wọn ninu, ni Ọlọrun nyin wi.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ tùú nínú, ẹ tu ènìyàn mi nínú, ni Ọlọ́run yín wí.