Isaiah 40:10 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ẹ wò ó! OLUWA Ọlọrun ń bọ̀ pẹlu agbára ipá rẹ̀ ni yóo fi máa ṣe àkóso. Ẹ wò ó! Èrè rẹ̀ ń bẹ lọ́wọ́ rẹ̀, ẹ̀san rẹ̀ sì ń bẹ níwájú rẹ̀.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, Oluwa Jehofah yio wá ninu agbara, apá rẹ̀ yio ṣe akoso fun u: kiyesi i, ère rẹ̀ wà pẹlu rẹ̀, ẹ̀san rẹ̀ si mbẹ niwaju rẹ̀.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wò ó, OLÚWA àwọn ọmọ-ogun náà ń bọ̀ wá pẹ̀lú agbára, apá rẹ̀ sì ń jọba fún un. Wò ó, ère rẹ̀ sì wà pẹ̀lúu rẹ̀, àti ìdápadà rẹ̀ tí ń bá a bọ̀ wá.