bible
ra
🌐 Language
English
Español
Français
Deutsch
Português
Italiano
Nederlands
Русский
中文
日本語
한국어
العربية
Türkçe
Tiếng Việt
ไทย
Indonesia
All Languages
Home
/
Bible
/
Compare Isaiah 40:23
Isaiah 40:23 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ẹni tí ó sọ àwọn ọba di ẹni ilẹ̀, ó sọ àwọn olóyè ayé di asán.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ẹniti o nsọ awọn ọmọ-alade di ofo; o ṣe awọn onidajọ aiye bi asan.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ó sọ àwọn ọmọ ọba di aṣán àti àwọn aláṣẹ ayé yìí ni ó ti sọ dòfo.