Isaiah 41:11 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Gbogbo àwọn tí wọ́n fẹ́ pa ọ́ run ni n óo dójú tì, wọn óo sì dààmú. Àwọn tí ń bá ọ jà yóo di asán, wọn óo sì ṣègbé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, gbogbo awọn ti o binu si ọ ni oju o tì, nwọn o si dãmu: nwọn o dabi asan; awọn ti o si mba ọ jà yio ṣegbe.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Gbogbo àwọn tí ó bínú sí ọ ni ojú yóò tì, tí wọn yóò sì di ẹni yẹ̀yẹ́; gbogbo àwọn tí ó lòdì sí ọ yóò dàbí asán, wọn yóò ṣègbé.