Isaiah 41:29 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Wò ó! Ìtànjẹ lásán ni gbogbo wọn, òfo ni iṣẹ́ ọwọ́ wọn: Ẹ̀fúùfù lásán ni àwọn ère tí wọ́n gbẹ́.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Kiyesi i, asan ni gbogbo wọn; asan ni iṣẹ wọn; ẹfũfu ati rudurudu ni ere didà wọn.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Kíyèsí i, irọ́ ni gbogbo wọn! Gbogbo ìṣe wọn já sí asán; àwọn ère wọn kò ṣé kò yà fún afẹ́fẹ́ àti dàrúdàpọ̀.