Isaiah 41:5 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
“Àwọn erékùṣù rí i, ẹ̀rù bà wọ́n, gbogbo òpin ayé gbọ̀n rìrì wọ́n ti súnmọ́ tòsí, wọ́n ti dé.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Awọn erekùṣu ri i, nwọn si bẹ̀ru; aiya nfò awọn opin aiye; nwọn sunmọ tosí, nwọn si wá.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Àwọn erékùsù ti rí i wọ́n bẹ̀rù; ìpẹ̀kun ilẹ̀ ayé wárìrì. Wọ́n súnmọ́tòsí wọ́n sì wá síwájú