Isaiah 42:12 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Kí wọn fi ògo fún OLUWA, kí wọn kéde ìyìn rẹ̀ ní àwọn erékùṣù.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Jẹ ki wọn fi ogo fun Oluwa, ki wọn si wi iyìn rẹ̀ ninu erekùṣu.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Jẹ́ kí wọn fi ògo fún OLÚWA àti kí wọn sì kéde ìyìn rẹ̀ ní erékùṣù.