Isaiah 42:15 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
N óo sọ àwọn òkè gíga ati àwọn kéékèèké di ilẹ̀, n óo mú kí gbogbo ewéko orí wọn gbẹ; n óo sọ àwọn odò di erékùṣù, n óo sì mú kí àwọn adágún omi gbẹ.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Emi o sọ oke-nla ati òke-kékèké di ofo, emi o si mú gbogbo ewebẹ̀ wọn gbẹ: emi o sọ odò ṣiṣàn di iyangbẹ́ ilẹ, emi o si mú abàta gbẹ.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Èmi yóò sọ òkè ńlá àti kékeré di ahoro tí n ó sì gbẹ gbogbo ewéko rẹ̀ dànù; Èmi yóò sọ àwọn odò di erékùṣù n ó sì gbẹ àwọn adágún.