Isaiah 42:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
A óo ká àwọn tí ó gbójú lé ère lọ́wọ́ kò, ojú yóo sì tì wọ́n patapata àwọn tí ń wí fún ère gbígbẹ́ pé: ‘Ẹ̀yin ni Ọlọrun wa.’ ” OLUWA ní:
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
A o dá awọn ti o gbẹkẹle ere gbigbẹ́ padà, a o doju tì wọn gidigidi, awọn ti nwi fun ere didà pe, Ẹnyin ni ọlọrun wa.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n àwọn tí ó gbẹ́kẹ̀lé òrìṣà, tí wọ́n wí fún ère pé, ‘Ẹ̀yin ni Ọlọ́run wa,’ ni a ó dá padà pẹ̀lú ìtìjú.