Isaiah 42:20 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Ó ń wo ọpọlọpọ nǹkan, ṣugbọn kò ṣe akiyesi wọn. Etí rẹ̀ là sílẹ̀, ṣugbọn kò gbọ́ràn.”
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ni riri nkan pupọ, ṣugbọn iwọ kò kiyesi i; ni ṣiṣi eti, ṣugbọn on ko gbọ́.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ẹ̀yin ti rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ nǹkan, ṣùgbọ́n ẹ kò ṣe àkíyèsí; etí yín yà sílẹ̀, ṣùgbọ́n ẹ kò gbọ́ nǹkankan.”