Isaiah 43:22 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
“Sibẹsibẹ, ẹ kò ké pè mí, ẹ̀yin ọmọ Jakọbu, ọ̀rọ̀ mi ti su yín, ẹ̀yin ọmọ Israẹli.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn iwọ kò ké pe mi, Jakobu; ṣugbọn ãrẹ̀ mu ọ nitori mi, iwọ Israeli.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
“Ṣíbẹ̀ ṣíbẹ̀ ìwọ kò tí ì ké pè mí, Ìwọ Jákọ́bù, àárẹ̀ kò tí ì mú ọ nítoríì mi Ìwọ Ísírẹ́lì.