Isaiah 45:17 — Compare Translations

3 translations compared side by side

Yoruba 2010
Ṣugbọn OLUWA gba Israẹli là, títí ayé sì ni ìgbàlà rẹ̀. Ojú kò ní tì ọ́, bẹ́ẹ̀ ni o kò ní dààmú, títí lae.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Ṣugbọn a o fi igbala ainipẹkun gba Israeli là ninu Oluwa: oju ki yio tì nyin, bẹ̃ni ẹ ki yio dãmu titi aiye ainipẹkun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Ṣùgbọ́n Ísírẹ́lì ni a ó gbàlà láti ọwọ́ OLÚWA Pẹ̀lú ìgbàlà ayérayé; a kì yóò kàn yín lábùkù tàbí kí a dójú tì yín, títí ayé àìnípẹ̀kun.