Isaiah 46:2 — Compare Translations
3 translations compared side by side
Yoruba 2010
Àwọn mejeeji jọ tẹríba, wọ́n jọ doríkodò, wọn ò lè gba àwọn ẹrù wọn kalẹ̀. Àwọn pàápàá yóo lọ sí ìgbèkùn.
Yoruba YBCV (Bibeli Mimọ)
Nwọn bẹ̀rẹ, nwọn jumọ tẹriba; nwọn kò le gbà ẹrù na silẹ, ṣugbọn awọn tikala wọn lọ si igbèkun.
Yoruba YCB (Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní)
Wọ́n bẹ̀rẹ̀ wọ́n sì foríbalẹ̀ papọ̀; wọn kò lè gba ẹrù náà, àwọn pẹ̀lú ni a kó lọ ní ìgbèkùn.